Christian Songs DownloadLyrics
[Music + Lyrics] Olorun Ni Yio Maje – Tope Alabi

[Music + Lyrics] Olorun Ni Yio Maje – Tope Alabi
Download song by the Nigerian Christian artist Tope Alabi titled “Olorun Ni Yio Maje“.
Download, listen, and be blessed:
Lyrics: Olorun Ni Yio Maje By Tope Alabi
Olorun ni yio ma je
Olorun ni yio ma je
Lana loni lola o, titi de ayeraye
Olorun ni yio ma je
Olorun ni yio ma je
Lana loni lola o, titi de ayeraye
Olorun ni yio ma je
Olorun ni yio ma je (Olorun ni yio ma je)
Olorun ni yio ma je (titi lai, titi lai, titi lai, titi lai)
Lana loni lola o (Lana o),
Titi de ayeraye (Loni o)
Olorun ni yio ma je (Titi Aye… Titi Aye)
Olorun ni yio ma je (titi lai, titi lai, titi lai, titi lai)
Lana loni lola o (Lana o),
Titi de ayeraye (Loni o)
Olorun ni yio ma je (Titi Aye… Titi Aye)
Alagbara ni ko se segun o
Ipa nla ni ko de le ku ooo
Aileyipada to la ye ni ikawo
Emi se’ba oluda orun o
(Emi se’ba oluda orun)
Ipa nla ni ko de le ku ooo
Aileyipada to la ye ni ikawo
Emi se’ba oluda orun o
(Emi se’ba oluda orun)
Olorun ni yio ma je (akoko nda olu nda aye)
Olorun ni yio ma je (patapata pira ogo nibi to pari si)
Lana loni lola o (patapata ola)
Titi de ayeraye
Olorun ni yio maje
Olorun ni yio ma je (patapata pira ogo nibi to pari si)
Lana loni lola o (patapata ola)
Titi de ayeraye
Olorun ni yio maje
Ailetuwa o ti wa ko to da orun
Tale ri ni ati titi loni
Eni ni igba ti o ni bere
Beni ko lopin
Mo juba akoda aye o
(Patapata ogo)
Tale ri ni ati titi loni
Eni ni igba ti o ni bere
Beni ko lopin
Mo juba akoda aye o
(Patapata ogo)
Olorun ni yio maje
(Eni lade to ti dade ka to d’aye)
Olorun…
(Eni lade to ti dade ka to d’aye)
Olorun…
Stay Safe!!!