[Music + Lyrics] Ibi Ire – Debbie Praise

[Music + Lyrics] Ibi Ire – Debbie Praise
MP3 download by the Nigeria Christian artist Abe Deborah who is popularly known as Debbie titled “Ibi Ire”
“Ibi Ire“ is a song inspired by God through the Holy Spirit. It is a song that motivates and inspires one to worship and pray to the Lord for a good place in life.
Download, listen, and be blessed:
Lyrics: Ibi Ire – Debbie Praise
Chorus
Ma je n tarakaki n to jeun
Eleda mi gbe mi de ibi ire
Ma je n taraka kin to se ohunrere
Ibi ire nimo n lo
Wamumi lo 2x
Verse 1
Oluorun ye
Ibirerelowu mi
Ma a je n se akobata fun egbe mi
Ma a ma je n shiletelayetimowa
Ibi ire lokan mi fe
Wa mu mi lo
Chorus
Ma je n tarakaki n to jeun
Eleda mi gbe mi de ibi ire
Ma je n taraka kin to se ohunrere
Ibi ire nimo n lo
Wamumi lo
Verse2
I know that I will move
and never stop
I know that I will shine so bright
I will succeed and never fail
God is my strength forever
Chorus
Ma je n tarakaki n to jeun
Eleda mi gbe mi de ibi ire
Ma je n taraka kin to se ohunrere
Ibi ire nimo n lo
Wamumi lo
Ibi ire nimo n lo
Baba wa mu mi de be
(Ibi ire nimo n lo baba wa mu mi lo)
Ki ma se akobata fun egbe mi layetimowababaaaa
(Ibi ire nimo n lo baba wa mu mi lo)
Ibi ire Ibi ire Ibi re o
nimofelayetimowayi
(Ibi ire nimo n lo baba wa mu mi lo)
Stay Safe!!!