Orisun Ogbon – Ogunmola Babajide
Orisun Ogbon – Ogunmola Babajide
This song gives hope for all situations. From life’s challenges to family issues and so on. If you need a song that motivates you not to give up on yourself, you need to consult “Orisun Ogbon” (Fountain of Wisdom).
Especially when things are going all wrong and you are discouraged, helpless, hopeless and there’s nowhere to turn to. God is there for you.
Download, listen, and be blessed:
Lyrics: Orisun Ogbon By Ogunmola Babajide
Orisun ogbon, Olorun Orisun Oye,
Oro Nigeria yi o do wo re,
Orisun ogbon o Jowo bawa tun to o.Ogbon wa ti jawa kule, koma ye wa mo oluwa,
Asise sise ise wa o mama yo,
laala yi poju, osise wa dabi ole,
Orisun ogbon oo jowo bawa tun to o
Olorun ko fara ni wa, awa lan nira wa lara,
Abo lowo oko eru, a tun kora wa leru oo
Ijinigbe, igbe sumomi yi ti poju Oluwa,
Orisun ogbon oo Jowo bawa dasi o e
Ologun ti see, won o mariise rara o,
Alagbada tun see nise lotun le koko si o
Afi kolorun, kobawa da soro yi o,
Orisun ogbon o, Jowo bawa tun to ooo
Ojojumo labiyamo n sunkun o
Ogun niwa, ogun leyin odowo re,
Awon oloriwa tise titi, koma ma yo,
Ajakale arun tao gboruko re ri lo gbode kan,
Afi korisun ogbon ko bawa yan ju oro yio
Onisegun nla o, Jowo wa wolee wa san.
Oni to ba ku ogbon feni keni kobeereo
Baba a un beere ogbon fawon aladariwa
Naijiria loruko Jesu gba ite si wa ju
Olorun mimo o jowo wa wo lee wa san.